Akopọ Iwadii
Jẹki A Sọrọ Nipa Rẹ
Isisinyi ni Akoko Naa
Mitapivat jẹ itọju tuntun kan ti ó ṣeeṣe fun awọn isoro irora ati sẹjẹdọlẹ ti àìsàn fòní kú fọ̀la nde. Títí dé ìhín awọn iwadii fun mitapivat meji ti wa — iwadii abala kekere 1 ati iwadii abala 2. Ni bayii abala RISE UP to kan, abala iwadii 3, jẹ iforukọ awọn Akọni silẹ.